Ikoko Akufo by Beautiful Nubia Audio, Video Download
In this evocative and lovely song titled Ikoko Akufo, innovative Nigerian artist Beautiful Nubia shares on the awesome and amazing experience of true love.
Enjoy and download!
Beautiful Nubia – Ikoko Akufo MP3
Watch the video below.
DOWNLOAD Beautiful Nubia – Ikoko Akufo MP4 Video Here
Ikoko Akufo Lyrics
Ikoko Akufo (Lamentation For A Broken Pot) Ikoko akufo, o d’ero akitan o
Ikoko to fo o, o ti dero akitan o
Monomono ya lu’gi, oro wo ‘nu ilu o
Itiju bi aso akisa lo ma ri o
O d’oro agbagba o, o d’eru f’ologbon
O d’owo awon agba o, o d’eru f’ologbon
Ilu Orita o, ilu alaafia
Mo ni t’e ba de’be, e ba mi ki won o
Gbogbo wa la o f’ayo de ‘le
Mo ni t’e ba ri o, e ba nk’
Awero yen o
Omoge awelewa to nda ni l’orun o
Ile owo ni o wo s’aya
Ile ola ni o wo s’aya o
Seb’ade ori oko ni won, obinrin to n’iwa t’o l’ewa
Iwuri obi ni won o ma je, mobinrin to gb’eko to mu lo
Ori re dara, ori re sunwon, o d’adufe olori oko
Ori re dara, ori re sunwon, o d’abefe o… Ikoko to fo i s’oun a mu se’be
Ikoko to fo i s’oun a mu to’le
Ikoko to fo i s’oun a mu r’odo
Ikoko to fo i s’oun a mu yan’gan
Ibadi aran d’eni a mu se yeye o
Bi eye ti o l’apa
Ibadi aran d’eni a mu se yeye o
O ba ma i lo o 2ce
Duro se’un obinrin nse
Gb’aye se’un obinrin nse